NEWS CELEBRITY ENTERTAINMENT FASHION HEALTH HOOK UP LEAKED LIFESTYLE MUSIC RELATIONSHIP VIDEOS

Friday, January 17, 2020

Toyin Abraham celebrates her man on his birthday

Get Best Daily Health Tips Here
Actress Toyin Abraham's beau and father of her son, Ire, Kolawole Ajeyemi is a year older today. And Toyin took to her instagram page to celebrate his special day with sweet words.

She wrote;
''Oko mi, ololufe mi, olowo ori mi @kolawoleajeyemi
Iwo ni eledumare fi se aso bo ihoho mi,
Iwo ni ete ti o je ki eyin mi di apoti isana
Iwo ni ejika ti ko je ki aso o ye lorun mi
Kolawole, iwo ni orun ti o gbe ori emi Toyin duro

Ni ojo eni to o je ayajo ojo ti a bi e saye, ni agbara eledumare, ire gbogbo ma wa e ri

Rere ni oju owo n ri, rere bayi ni oju e ma ma ri.
Eyan bi esu, esu bi eyan ti o ma n fi ikoro si nkan ti o n dun o ni fi ikoro si Ife wa ni agbara Olorun

Iwo ni irawo owuro mi, Irawo e o ni wo okunkun

Akolawole, Odun tuntun yi a san e s'owo, a san e s'omo, a san e si alafia ati emi gigun.
Happy birthday my love. Ife wa, titi laye laye ni.
I love you now and forever❤️❤️❤️❤️❤️''


Related Posts:

0 comments:

Post a Comment